top of page
Ẹ̀yin ni Ìmọ́lẹ̀ Aiyé
Matiu 5:14
Baba ìyọ́nú àti Ọlọ́run ìtùnú gbogbo, ńtù wá nínú ni gbogbo ìdààmú wa, ki àwa pẹ̀lú lè máa tu àwọn tí ó wá nínú ìdààmú nínú, nípá ìtùnú náà ti a fi ńtú àwa fúnra wa nínú láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá. (2 Kọrinti 1:3-4)
Click an image to send or download a Life-Changing Message
bottom of page